Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 26:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Àwọn tí ọwọ́ wọn kún fún ìwà ibi,tí ọwọ́ ọ̀tún wọn kún fún àbẹ̀tẹ́lẹ̀.

11. Ṣùgbọ́n èmi ó máa rìn nínú ìwà títọ́;rà mí padà, kí o sì ṣàánú fún mi.

12. Ẹsẹ̀ mi dúró lórí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú;nínú ìjọ ńlá èmi yóò fi ìbùkún fún Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 26