Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 25:19-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Kíyẹ̀sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀tá mi,tí wọn kórìírá a mi pẹ̀lú ìwà ìkà wọn.

20. Pa ọkàn mi mọ́, kí o sì gbà mí sílẹ̀;Má ṣe jẹ́ kí a fi mí sínú ìtìjú,nítorí pé ìwọ ni ibi ìsádi mi.

21. Jẹ́ kí òtítọ́ inú àti ìdúró ṣinṣin kí ó pa mí mọ́;nítorí pé mo dúró tì ọ́.

22. Ra Ísírẹ́lì padà, Ìwọ Ọlọ́run,nínú gbogbo ìṣòro Rẹ̀!

Ka pipe ipin Sáàmù 25