Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 24:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ti Olúwa ni ilẹ̀, àti ẹ̀kún Rẹ̀,ayé àti àwọn tí ó tẹ̀dó sínú Rẹ̀;

2. Nítorí ó fi ìpìlẹ̀ Rẹ̀ lélẹ̀ lórí òkunó sì gbée kalẹ̀ lórí àwọn ìṣàn omi.

3. Ta ni yóò gun òrí òkè Olúwa lọ?Ta ni yóò dúró ní ibi mímọ́ Rẹ̀?

Ka pipe ipin Sáàmù 24