Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ni àpáta àti odi mi, àti olùgbàlà mi;Ọlọ́run mi ni àpáta mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ìsádi mi.Òun ni àpáta ààbò àti agbára ìgbàlà mi àti ibi ìsádi mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 18

Wo Sáàmù 18:2 ni o tọ