Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 17:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gbọ́, Olúwa, ẹ̀bẹ̀ òtítọ́ mi;fi etí sí igbe mi.Tẹ́ti sí àdúrà mití kò ti ètè ẹ̀tàn jáde.

2. Kí ìdáláre mi wá láti ọ̀dọ̀ Rẹ;kí ojú Rẹ kí ó rí ohun tí ó tọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 17