Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 16:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Pa mí mọ́, Ọlọ́run,nítorí nínú Rẹ ni ààbò mí wà.

2. Mo sọ fún Olúwa, “ìwọ ni Ọlọ́run mi,lẹ́yìn Rẹ èmi kò ní ire kan.”

3. Sí àwọn ènìyàn tí ó wà ní ayé,àwọn ni ológo nínú èyí tí ayọ̀ mí wà.

4. Ìṣòro àwọn wọ̀n ọn nì yóò pọ̀ síiàwọn tí ń tọ ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn.Ẹbọ ohun mímu ẹ̀jẹ̀ wọn ni èmi kì yóò ta sílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò dá orúkọ wọn lẹ́nu mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 16