Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 150:3-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Ẹ fi ohùn ìpè, yìn ín.Ẹ fi ohun èlò orin yìn ín.

4. Ẹ fi ohun èlò orin àti ijó yìn ínfi ohun èlò orin olokùn àti ìpè yìn ín

5. Ẹ yìn ín pẹ̀lú aro olóhùn òkè.Ẹ yìn ín lára aro olóhùn gooro

6. Jẹ́ kí gbogbo ohun tí ó ní ẹ̀mí yin Olúwa.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 150