Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 150:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.Ẹ fi ìyìn fún Ọlọ́run ní ibi mímọ́ Rẹ̀Ẹ yìn ín nínú agbára ọ̀run Rẹ̀.

2. Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ agbára Rẹ̀.Ẹ yìn ín fún títóbi Rẹ̀ tí ó tayọ̀.

3. Ẹ fi ohùn ìpè, yìn ín.Ẹ fi ohun èlò orin yìn ín.

4. Ẹ fi ohun èlò orin àti ijó yìn ínfi ohun èlò orin olokùn àti ìpè yìn ín

5. Ẹ yìn ín pẹ̀lú aro olóhùn òkè.Ẹ yìn ín lára aro olóhùn gooro

Ka pipe ipin Sáàmù 150