Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 15:2-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Ẹni tí ń rìn déédéétí ó sì ń sọ òtítọ́,láti inú ọkàn Rẹ̀

3. tí kò fi ahọ́n Rẹ̀ sọ̀rọ̀ ẹni lẹ́yìn,tí kò ṣe ibi sí aládùúgbò Rẹ̀tí kò sì sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí ẹnìkejì Rẹ̀,

4. ní ojú ẹni tí ènìyàn-kénìyàn di gígànṣùgbọ́n ó bọ̀wọ̀ fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa,Ẹni tí ó búra sí ibi ara Rẹ̀àní tí kò sì yípadà,

5. tí ó ń yá ni lówó láìsí èlékò sì gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ lòdì sí aláìlẹ́ṣẹ̀.Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe èyíni a kì yóò mì láéláé.

Ka pipe ipin Sáàmù 15