Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 15:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, Ta ni yóò máa gbé nínú àgọ́ mímọ́ Rẹ?Ta ni yóò máa gbé ní òkè mímọ́ Rẹ?

2. Ẹni tí ń rìn déédéétí ó sì ń sọ òtítọ́,láti inú ọkàn Rẹ̀

Ka pipe ipin Sáàmù 15