Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 148:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé ìwo kan sókè fún àwọn ènìyàn Rẹ̀,ìyìn fún gbogbo ènìyàn mímọ́ Rẹ̀ àní fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,àwọn ènìyàn tí ó súnmọ́ ọ̀dọ̀ Rẹ̀.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 148

Wo Sáàmù 148:14 ni o tọ