Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 148:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ìyìn fún OlúwaẸ fi ìyìn fún Olúwa láti ọ̀run wáẸ fi ìyìn fún un níbi gíga

2. Ẹ fi ìyìn fún un,gbogbo ẹ̀yin ángẹ́lì Rẹ̀Ẹ fi ìyìn fún un,gbogbo ẹ̀yin ọmọ ogun Rẹ̀

3. Ẹ fi ìyìn fún un,oòrùn àti òṣùpáẸ fi ìyìn fún un,gbogbo ẹ̀yin ìràwọ̀ ìmọ́lẹ̀.

4. Ẹ fi ìyìn fún un,ẹ̀yin ọ̀run àwọn ọ̀run gígaàti ẹ̀yin omi tí ń bẹ ní òkè ọ̀run

5. Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ Olúwanítorí ó pàṣẹ a sì dá wọn

Ka pipe ipin Sáàmù 148