Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 147:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Olúwa wa pẹ̀lú àwọn onírẹ̀lẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ó Rẹ̀ àwọn ènìyàn búburú sílẹ̀.

7. Fi ọpẹ́ kọrin sí Olúwafi ohun èlò orin olókùn yin Ọlọ́run.

8. Ó fi ìkuukù bo àwọ sánmọ̀ó rọ òjò sí orílẹ̀ ayéó mú kí koríko hù lórí àwọn òkè

Ka pipe ipin Sáàmù 147