Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 147:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ìyìn fún Olúwa nítorí ohun rereláti máa kọrin ìyìnsí Ọlọ́run wa,ó yẹ láti kọrin ìyìn síi.

2. Olúwa kọ́ Jérúsálẹ́mù;O ko àwọn Ísírẹ́lì tí a lé sọnù jọ.

3. Ó wo àwọn tí ọkàn wọ́n bajẹ́ sànó sì di ọgbẹ́ wọn.

Ka pipe ipin Sáàmù 147