Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 145:9-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Olúwa dára sí ẹni gbogbo;ó ní àánú lóri ohungbogbo tí ó dá.

10. Gbogbo ohun tí ìwọ ti dá niyóò máa yìn ọ́ Olúwa;àwọn ẹni mímọ́ yóò máa pòkìkí Rẹ.

11. Wọn yóò sọ ògo ìjọba Rẹwọn yóò sì sọ̀rọ̀ agbára Rẹ,

12. Kí gbogbo ènìyàn le mọ isẹ́ agbára rẹ̀àti ola ńlá ìjọba Rẹ tí ó lógo.

13. Ìjọba Rẹ ìjọba ayérayé ni,àti ìjọba Rẹ wà ní gbogbo ìran-díran.

14. Olúwa mú gbogbo àwọn tí ó ṣubú róó sì gbé gbogbo àwọn tí ó tẹríba dìde.

Ka pipe ipin Sáàmù 145