Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 145:7-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Wọn yóò ṣe ìrántí ọ̀pọ̀lọpọ̀ìwà rere Rẹ àti orin ayọ̀ òdodo Rẹ.

8. Olore òfẹ́ ni Olúwa àti aláàánúó lọ́ra láti bínú ó sì ní ìfẹ́ púpọ̀,

9. Olúwa dára sí ẹni gbogbo;ó ní àánú lóri ohungbogbo tí ó dá.

10. Gbogbo ohun tí ìwọ ti dá niyóò máa yìn ọ́ Olúwa;àwọn ẹni mímọ́ yóò máa pòkìkí Rẹ.

11. Wọn yóò sọ ògo ìjọba Rẹwọn yóò sì sọ̀rọ̀ agbára Rẹ,

Ka pipe ipin Sáàmù 145