Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 145:15-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Ojú gbogbo ènìyàn ń wò ọ́,ó sì fún wọn ní oúnjẹ wọn ní àkókò tí ó yẹ

16. Ìwọ sí ọwọ́ Rẹìwọ sì tẹ́ ìfẹ́ gbogbo ohun alààyè lọ́rùn.

17. Olúwa jẹ́ olódodo ní gbogbo ọ̀nà Rẹ̀àti ìfẹ́ Rẹ̀ sí gbogbo ohun tí o dá.

18. Olúwa wà ní tòsí gbogbo àwọn tí ń ké pè é,sí gbogbo ẹni tí ń ké pè é ní òtítọ́.

19. Ó mú ìfẹ́ àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀ ṣẹ;ó gbọ́ igbe wọn, ó sì gbà wọ́n.

Ka pipe ipin Sáàmù 145