Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 143:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa gbọ̀ àdúrà mi,fetísí igbe mi fún àánú;nínú òtítọ́ àti òdodo Rẹ wá fún ìrànlọ́wọ́ mi

2. Má ṣe mú ìránṣẹ́ Rẹ wá sí ìdájọ́,nítorí kò sí ẹnìkan tí ó wà láàyètí ó ṣe òdodo níwájú Rẹ.

3. Ọ̀ta ń lé pa mi,ó fún mi pa mọ́ ilẹ̀;ó mú mi gbé nínú òkùnkùnbí àwọn tí ó ti kú ti pẹ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 143