Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 142:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ẹ̀mí mi ṣààrẹ̀ nínú mi,ìwọ ni ẹni tí ó mọ ọ̀nà mi.Ní ipa ọ̀nà tí èmi ń rìnènìyàn ti dẹ okùn fún mi ní ìkọ̀kọ̀

Ka pipe ipin Sáàmù 142

Wo Sáàmù 142:3 ni o tọ