Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 141:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Mú kí ìsṣ ṣọ́ ẹnu mi, Olúwa:kí o sọ̀ máa pa ilẹ̀kùn ètè mi mọ́.

4. Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun tí ń ṣe ibi,Láti máa bá àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ búburúmá sì ṣe jẹ́ kí èmi jẹ́ àdídùn wọn.

5. Jẹ́ kí olódodo lù mí: ìṣeun ni ó jẹ́:jẹ́ kí ó bá mi wí, ó jẹ́ òróró ní orí mi.Tí kì yóò fọ́ mí ní orí.Ṣíbẹ̀ àdúrà mi wá láí sí ìṣe àwọn olùṣe búburú

Ka pipe ipin Sáàmù 141