Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 138:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi yóò yìn ọ́ tinú tinú mi gbogbo;níwájú àwọn òrìṣà ní èmi ó kọrin ìyìn sí ọ.

2. Èmi ó máa gbàdúrà sí ìhà tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ̀èmi ó sì máa yin orúkọ Rẹnítorí ìṣeun ìfẹ́ Rẹ àti òtítọ́ Rẹ;nítorí ìwọ gbé ọ̀rọ̀ Rẹ ga ju orúkọ Rẹ lọ.

3. Ní ọjọ́ tí mo képè ọ́, ìwọ dá mi lóhùn,ìwọ sì fi ipa mú mi lára le ní ọkàn mi.

4. Gbogbo àwọn ọba ayé yóò yìn ọ́, Olúwa, ní ìgbà tí wọn bá gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu Rẹ

Ka pipe ipin Sáàmù 138