Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 135:19-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Ẹ̀yin ara ilé Ísírẹ́lì, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa,ẹ̀yin ará ilé Árónì, fi ìbùkún fún Olúwa.

20. Ẹ̀yin ará ilé Léfì, fi ìbùkún fún Olúwa;ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Olúwa, fi ìbùkún fún Olúwa.

21. Olùbùkún ní Olúwa, láti Síónì wá,tí ń gbé Jérúsálẹ́mù. Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 135