Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 130:3-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Olúwa, ìbáṣe pé kí ìwọ kí o máa ṣàmì ẹ̀ṣẹ̀, Olúwa, tà ni ìbá dúró.

4. Nítorí ìdàríjìn wà lọ́dọ̀ Rẹ,kí a lè máa bẹ̀rù Rẹ.

5. Èmi dúró de Olúwa, ọkàn mi dúró,àti nínú ọ̀rọ̀ Rẹ ni èmi ń ṣe ìrètí

6. Ọkàn mi dúró de Olúwa,ju àwọn tí ń ṣọ́nà òwúrọ̀ lọ,àní ju àwọn ti ń ṣọ́nà òwúrọ̀ lọ.

Ka pipe ipin Sáàmù 130