Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 130:2-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Olúwa, gbóhùn mi,jẹ́ kí etí Rẹ̀ kí o tẹ́ sílẹ̀ sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.

3. Olúwa, ìbáṣe pé kí ìwọ kí o máa ṣàmì ẹ̀ṣẹ̀, Olúwa, tà ni ìbá dúró.

4. Nítorí ìdàríjìn wà lọ́dọ̀ Rẹ,kí a lè máa bẹ̀rù Rẹ.

5. Èmi dúró de Olúwa, ọkàn mi dúró,àti nínú ọ̀rọ̀ Rẹ ni èmi ń ṣe ìrètí

Ka pipe ipin Sáàmù 130