Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 130:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Láti inú ibú wá níèmi ń képè ọ Olúwa

2. Olúwa, gbóhùn mi,jẹ́ kí etí Rẹ̀ kí o tẹ́ sílẹ̀ sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.

3. Olúwa, ìbáṣe pé kí ìwọ kí o máa ṣàmì ẹ̀ṣẹ̀, Olúwa, tà ni ìbá dúró.

4. Nítorí ìdàríjìn wà lọ́dọ̀ Rẹ,kí a lè máa bẹ̀rù Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 130