Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 13:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa? Ìwọ o ha gbàgbé mi títí láé?yóò tí pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa fi ojú Rẹ pamọ́ fún mi?

2. Yóò ti pẹ́ tó tí èmi ó máa bá èrò mi jà,àti ní ojojúmọ́ ni èmi ń ní ìbànújẹ́ ní ọkàn mi?Yóò ti pẹ́tó tí àwọn ọ̀ta mi yóò máa borí mi?

3. Wò mí kí o sì dá mi lóhùn, Olúwa Ọlọ́run mi.Fi ìmọ́lẹ̀ fún ojú mi, kí èmi ó má sùn oorun ikú;

Ka pipe ipin Sáàmù 13