Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 124:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Olùbùkún ni Olúwa, tí kò fi wá fún wọ́nbí ohun ọdẹ fún eyín wọn.

7. Ọkàn wa yọ bí ẹyẹ jáde kúrò nínú okùn apẹyẹ;okùn já àwa sì yọ.

8. Ìrànlọ́wọ́ wa ń bẹ ní orúkọ Olúwa,tí ó dá ọ̀run òun ayé.

Ka pipe ipin Sáàmù 124