Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 123:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Kíyèsí, bí ojú àwọnìránṣẹ́ kùnrin ti máa ń wo ọwọ́ àwọn baba wọn,àti bí ojú ìránṣẹ́-bìnrin ti máa ń wo ọwọ́ ìyá Rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Olúwa Ọlọ́run wa,títí yóò fi ṣàánú fún wa.

3. Olúwa, ṣàánú fún wa, ṣàánú fún wa;nítorí tí a kún fún ẹ̀gàn púpọ̀ púpọ̀.

4. Ọkàn wa kún púpọ̀ fún ẹ̀gàn àwọn onírera,àti fún ẹ̀gàn àwọn agbéraga.

Ka pipe ipin Sáàmù 123