Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 121:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Oòrùn kì yóò pa ọ ní ìgbà ọ̀sántàbí òṣùpá ní ìgbà òru.

7. Olúwa yóò pa ọ́ mọ́ kúrò nínú ibi gbogboyóò pa ọkàn Rẹ mọ́

8. Olúwa yóò pa àlọ àti ààbọ̀ Rẹ mọ́láti ìgbà yìí lọ àti títí láéláé.

Ka pipe ipin Sáàmù 121