Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 121:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi yóò gbé ojú mi sórí òkè wọ̀n-ọn-nì—níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá

2. Ìrànlọ́wọ́ mi tí ọwọ́ Olúwa wáẸni tí ó dá ọ̀run òun ayé

3. Òun kì yóò jẹ́ kí ẹṣẹ̀ Rẹ̀ kí ó yẹ̀;ẹni tí ó pa ọ́ mọ́ kì í tòògbé.

Ka pipe ipin Sáàmù 121