Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 119:56-61 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

56. nitori ti mogba ẹ̀kọ́ Rẹ gbọ́.

57. Ìwọ ni ìpín mi, Olúwa:èmi ti pinnu láti tẹríba sí ọ̀rọ̀ Rẹ.

58. Èmi ti wá ojú Rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi:fún mi ní oore ọ̀fẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìpinnu Rẹ.

59. Èmi ti kíyèsí ọ̀nà mièmi sì ti gbé ìgbésẹ̀ mi sí òfin Rẹ.

60. Èmi yóò yára, ń kò ni lọ́raláti gbọ́ràn sí àṣẹ Rẹ.

61. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ẹni búburú dì mí pẹ̀lú okùn,èmi kò ní gbàgbé òfin Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 119