Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 119:167-172 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

167. Èmi gba òfin Rẹ gbọ́,nítorí mo fẹ́ràn wọn púpọ̀ púpọ̀

168. Èmi ṣe ìgbọ́ràn sí ẹ̀kọ́ Rẹ àti òfin Rẹ,nítorí ìwọ mọ gbogbo ọ̀nà mi.

169. Jẹ́ kí igbe mi wá sí iwájú Rẹ, Olúwa;fún mi ní òye gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Rẹ.

170. Jẹ́ kí ẹ̀bẹ̀ mi wá sí iwájú Rẹ;gbà mí gẹ́gẹ́ bí ìpinnu Rẹ.

171. Ètè mi yóò sọ ìyin jáde,nítorí ìwọ kọ́ mi ní ọ̀nà Rẹ.

172. Jẹ́ kí ahọ́n mi kọ orin ọ̀rọ̀ Rẹ,nítorí gbogbo àṣẹ Rẹ jẹ́ òdodo.

Ka pipe ipin Sáàmù 119