Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 116:5-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Olúwa ní oore-ọ̀fẹ́ ó sì ní òdodo;Ọlọ́run wa kún fún àánú.

6. Olúwa pa àwọn ọlọ́kàn fífúyẹ́ mọ́nígbà tí mo wà nínú àìní ńlá, ó gbà mí.

7. Padà, ìwọ ọkàn mi, sí ibi ìsinmi Rẹ,nítorí Olúwa ṣe dáradára sí ọ.

8. Nítorí ìwọ, Olúwa, ti gba ọkàn mikúrò lọ́wọ́ ikú,ojú mi kúrò lọ́wọ́ omijé,àti ẹsẹ̀ mi kúrò lọ́wọ́ ìṣubú,

9. Nítorí èmi yóò máa rìn níwájú Olúwaní ilẹ̀ alààyè.

Ka pipe ipin Sáàmù 116