Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 116:16-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Olúwa, ní tòótọ́ ìránṣẹ́ Rẹ ni mo jẹ́;èmi ni ìránṣẹ́ Rẹ, ọmọ ìránṣẹ́-bìnrin Rẹ;ó ti tú mi sílẹ̀ nínú ìdè mi.

17. Èmi yóò rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọèmi yóò sì képe orúkọ Olúwa

18. Èmi yóò mú ìlérí mi sẹ sí Olúwaní ojú gbogbo àwọn ènìyàn Rẹ̀,

19. Nínú àgbàlá ilé Olúwani àárin Rẹ̀, ìwọ Jérúsálẹ́mù.Ẹ yin Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 116