Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 116:12-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Kí ni èmi yóò san fún Olúwanítorí gbogbo rere Rẹ̀ sí mí?

13. Èmi yóò gbé aago ìgbàlà sókèèmi yóò sì máa ké pe orúkọ Olúwa.

14. Èmi yóò mú ìlérí mi ṣẹ sí Olúwaní ojú àwọn ènìyàn Rẹ̀.

15. Iyebíye ní ojú Olúwaàti ikú àwọn ẹni mímọ́ Rẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 116