Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 112:8-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. Ó ti mú ọkàn Rẹ̀ gbilẹ̀, ẹ̀rù kí yóò bàá,títí yóò fi rí ìfẹ́ ọkan Rẹ̀ lórí àwọn ọ̀tá Rẹ̀.

9. Ó ti pin ká, ó ti fi fún àwọn olùpọ́njú;Nítorí òdodo Rẹ̀ dúró láé;ìwọ Rẹ̀ ní a ó gbé sókè pẹ̀lú ọlá.

10. Ènìyàn búburú yóò rí, inú wọn yóò sì bàjẹ́,yóò sì pa eyín keke, yó sì yọ dànù:èròngbà ọkàn ènìyàn búburú ni yóò ṣègbé.

Ka pipe ipin Sáàmù 112