Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 112:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ìyìn fún Olúwa. Ìbùkún ni fún Ọkùnrin náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run,tí ó ní inúdídùn ńlá sí àwọn òfin Rẹ̀.

2. Iru ọmọ Rẹ̀ yóò jẹ́ alágbára ní ayé:ìran àwọn olóòótọ́ ni a ó bùkún fún

3. Ọlá àti ọrọ̀ yóò wà nínú ilé Rẹ̀:òdodo Rẹ̀ sì dúró láé.

4. Fún olóòótọ́ ni ìmọ́lẹ̀ yóò tàn fún ni òkùnkùn:olóore ọ̀fẹ́ àti aláàánú àti òdodo.

Ka pipe ipin Sáàmù 112