Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 108:9-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Móábù si ni ìkòkò ìwàsẹ̀ milórí Édómù ní èmi ó bọ́ bàtà mi sílórí òkè Fílísitínì ni èmi yóò hó ìhó ayọ̀.”

10. Ta ni yóò mú mi wá sí ìlú olódiTa ni yóò sìn mi wá sí Édómù

11. Ìwọ Ọlọ́run há kọ́, ìwọ tí ó ti kọ̀ wá sílẹ̀Ọlọ́run ìwọ kì yóò bá àwọn jagunjagun wa jáde mọ́.

12. Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ nínú ìpọ́njúnítorí ìrànlọ́wọ́ ènìyàn asán ni

13. Nípaṣẹ̀ Ọlọ́run ni àwa ó ṣe akinnítorí oun ó tẹ àwọn ọ̀ta wa mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 108