Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 107:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ó ṣeun;nítorí ìfẹ́ Rẹ̀ dúró láéláé.

2. Jẹ́ kí àwọn ẹni ìràpadà Olúwa kí ó wí bayí, àwọnẹni tí ó ràpadà kúrò lọ́wọ́ ọ̀tá,

3. Àwọn tí ó kó jọ láti ilẹ̀ wọ̀nnìláti ìlà òòrùn àti ìwọ̀ òòrùn,láti àríwá àti òkun wá.

Ka pipe ipin Sáàmù 107