Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 104:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. O fi ayé gúnlẹ̀ lórí àwọn ìpìlẹ̀;tí a kò le è mi láéláé.

6. Ìwọ fi ibú omi bò ó mọ́lẹ̀ bí aṣọ;àwọn omi sì dúró lórí àwọn òkè ńlá.

7. Ṣùgbọ́n nípa ìbáwí Rẹ ni àwọn omi lọ,nípa ohùn àrá Rẹ ni wọ́n sálọ;

Ka pipe ipin Sáàmù 104