Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 104:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi. Olúwa Ọlọ́run mi, ìwọ tóbi jọjọ; ọlá àti ọlá ńláni ìwọ wọ̀ ní aṣọ.

2. Ìwọ fi ìmọ́lẹ̀ bo ara Rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣọ;ó tẹ ọ̀run bí títẹ́ ẹní

3. Ìwọ tí ó fi omi ṣe ìtì igi-àjà ìyẹ̀wù Rẹ.Ìwọ ti ó ṣe àwọ̀sánmọ̀ ni kẹ̀kẹ́-ogun Rẹìwọ tí ó ń rìn lórí àpá ìyẹ́ afẹ́fẹ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 104