Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 104:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi. Olúwa Ọlọ́run mi, ìwọ tóbi jọjọ; ọlá àti ọlá ńláni ìwọ wọ̀ ní aṣọ.

2. Ìwọ fi ìmọ́lẹ̀ bo ara Rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣọ;ó tẹ ọ̀run bí títẹ́ ẹní

Ka pipe ipin Sáàmù 104