Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 103:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Yin Olúwa, ìwọ ọkàn mi, kí o má ṣe gbàgbé gbogbo oore Rẹ̀

3. Ẹni tí ó dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ̀ jìn ọ́ tíó sì wo gbogbo àrùn Rẹ̀ sàn,

4. Ẹni tí o ra ẹ̀mí Rẹ padà kúrò nínú kòtò ikúẹni tí o fi ìṣeun ìfẹ́ àti ìyọ́nú dé ọ ní adé,

Ka pipe ipin Sáàmù 103