Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 102:6-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Èmi dà bí ẹyẹ igún ni ijù:èmi dàbí òwìwí ibi ahoro.

7. Èmi dìde; èmí dàbí ẹyẹ lórí ilé.

8. Ní ọjọ́ gbogbo àwọn ọ̀ta ológosẹ́ mi ń gàn mí;àwọn tí ń ṣe ìkanra sí mi ń fi orúkọ mi bú.

9. Èmi jẹ eérú gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ mi, èmi si da ohun mímu mi pọ̀ pẹ̀lú omíjé.

10. Nítorí ìbínú ríru Rẹ, nítorí ìwọ ti gbé mi sókè, ìwọ sì gbé mi ṣánlẹ̀.

11. Ọjọ́ mi dàbí òjìji àṣálẹ́èmi sì rọ bí koríko

12. Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, ni yóò dúró láéláé;ìrántí Rẹ láti ìran dé ìran.

Ka pipe ipin Sáàmù 102