Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 102:26-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Wọn yóò ṣègbé, wọn yóò parun, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà;gbogbo wọn ni yóò gbó bí aṣọ.Bí ẹ̀wù ni ìwọ yóò pààrọ̀ wọnwọn yóò sì di àpatì.

27. Ṣùgbọ́n ìwọ wà digbí ṣíbẹ̀,ọdún Rẹ kò sì ni òpin.

28. Àwọn ọmọ ìránṣẹ́ Rẹ̀ yóò dúró ní iwájú Rẹ pẹ́;a o sì fi ẹsẹ̀ irú ọmọ wọn sọlẹ̀ ní iwájú Rẹ.”

Ka pipe ipin Sáàmù 102