Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 4:17-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Àwọn obìnrin àdúgbò sì wí pé, “A bí ọmọkùnrin kan fún Náómì.” Wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Óbédì. Òun sì ni baba Jésè tí í ṣe baba Dáfídì.

18. Èyí ni ìran Pérésì:Pérésì ni baba Ésírónì,

19. Ésírónì ni baba Rámú,Rámù ni baba Ámínádábù

20. Ámínádábù ni baba Násónì,Násónì ni baba Sálímónì,

Ka pipe ipin Rúùtù 4