Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àfikún, mo ra Rúùtù ará Móábù opó Málíónì padà láti di aya mi. Èyí tí yóò mú kí orúkọ ọkùnrin òkú náà wà pẹ̀lú ohun-ìní rẹ̀, kí ìran rẹ̀ má ba à lè parẹ́ láàrin àwọn ẹbí rẹ̀ àti ìlú rẹ̀. Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí ní òní.”

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:10 ni o tọ