Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù sì bá àwọn ìránṣẹ́-bìnrin Bóásì ṣiṣẹ́ títí tí wọ́n fi parí ìkórè ọkà bálì àti ti jéró. Ó sì ń gbé pẹ̀lú ìyá ọkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:23 ni o tọ