Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù, ará Móábù sì wí fún Náómì pé, “Jẹ́ kí èmi kí ó lọ sí inú oko láti ṣa ọkà tí àwọn olùkórè fi sílẹ̀ ní ọ̀dọ̀ ẹnikẹ́ni tí èmi yóò bá ojú rere rẹ̀ pàdé.”Náómì sì sọ fún-un pé, “Má a lọ, ọmọbìnrin mi.”

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:2 ni o tọ