Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù sì ń ṣa ọkà títí ó fi di ìrọ̀lẹ́, nígbà tí ó sì pa ọkà tí ó rí ṣà, tí ó sì fẹ́ ẹ tán, èyí tí ó rí sì tó ìwọ̀n garawa kan (lítà méjìlélógún).

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:17 ni o tọ